REMO ANTHEM
Eesoe Eesoe Eesoe
Eesoe Eesoe Eesoe
Awa Remo lati Iremo lo gbode
Ibi oju tinmo wa lorirun wa
Ilu metalelogbon ri dede eni
Lomode lagba lokunren nobiren
L’Oba ni ‘Joye ka jagun molu
Abowo fun awon agba totilo
Areee
E hoo ihoo ayo
E hoo ihoo ayo
Ureyin eluife
Remoo busan Remoo busan
Dede oni ree maa sori ire
We use cookies to analyze website traffic and optimize your website experience. By accepting our use of cookies, your data will be aggregated with all other user data.